Okan balè o Okan balè o Okan balè o Okan balè o Emi ni kan ko ló wa la yé Omo dada lé mi Moni ebí pupó Momo gbogbó ibí témi laye Iri si dada ni témi e gbo o Momo pe éfe ran mí, éje ki n mo Dupé fun yin Ife yin fun mi layo Mo fe ki aye temi ko da Iya mi o, pélú baba mí (baba mí) Awon aburo mi n ko? (Baba mí) Mo n de dupé fun olúwa o (baba mí) To fun mí lébí tóda yi (baba mi) Mo n dupe fun ayé yí o Ododún maré mo n dupe Okan balè o Okan balè o Eni ti o ba nífe ninu ayé Pelú ebí dada óluwaré ajiya Gbogbo wa ninu aya wa ifé Kadúpe ti awa ba ri ife dada Momo pe éfe ran mí, éje ki n mo Dupé fun yin Ife yin fun mi layo, mo fe ki aye temi ko da Iya mi o, pélú baba mí (baba mí) Awon aburo mi n ko? (Baba mí) Mo n de dupé fun olúwa o (baba mí) To fun mí lébí tóda yi (baba mi) Modupe fun ayé yí o Ododún maré mo n dupe