Oun gbogbo to fo s'oke, o ṣí n bọ wa'lẹ Ìyẹn l'ọrọ ile aye Oun ire ta m'ọwọ wa ṣe, ni yi o sun wa s'ayọ o Ire awa ko ni kọjá Oṣíṣẹ ki ṣ'ofo, ireti le pe l'oju ẹda o Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa Lo n pe o, lo n pe mi o O n pe o, o n pe mi o O n ba wa wi Wi f'ẹni to n bẹru, ko ma ṣe ṣ'iyemeji Igboya ni t'olubori Sọ f'àwọn to n ṣe'paya o, duro ko ma-ma mi'kan o Aforiti l'ọpá ogo Ọmọ ọgbọn kii foya, ileri ko ni ṣá ii ṣẹ o Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa Lo n pe o, lo n pe mi o O n pe o, o n pe mi o O n ba wa wi Irinajo ọmọ ẹda o n la ti loke-nilẹ Ìyẹn l'ọrọ ile aye Oun ire ta fẹ gbeṣe, ni yi o sun wa si'dunnu Ayọ abakalẹ Oṣíṣẹ kii ṣ'ofo, ireti le pe l'oju ẹda o Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa Lo n pe o, lo n pe mi o O n pe o, o n pe mi o O n ba wa wi O n pe o, o n pe mi o O n ba wa wi o O n pe o, o n pe mi o O n ba wa wi Ṣé b'on, o n pe o, o n pe mi o O n ba wa wi o O n pe o, o n pe mi o Ṣé bo n ba wa wi O n pe o