Níbí wọn gbé ń ṣe'un tó yẹ kà ṣé láyé o Níbí wọn gbé ń ṣe'un tó dára, ọrẹ (ọrẹ) Níbí wọn gbé ń ṣeré aládùn, 'ládùn, 'ládùn, 'ládùn Níbí wọn gbé ń ṣ'ájọyọ tẹrín-tọyaya ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ṣé b'áwọn lo l'érè òní ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo ẸniỌbankẹ o (ìtànṣán oòrùn) ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o Kà lọ, kà jọ débẹ o, woah-oh-oh Ke s'ọmọdé pẹ'lú ọdọ, èwe àti májesìn Ke s'ọkùnrin pel'ọkùnrin, àgbààgbà ìlù Ke s'ẹní tí ńbẹ l'okò, tí ń ṣíṣẹ kò le dá Ke s'ẹní tó re, tí ò l'àgbàrá mọ Wípé, ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ṣé b'áwọn lo l'érè òní ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo o ẸniỌbankẹ o (ìtànṣán oòrùn) ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o Kà lọ, kà jọ débẹ o, yea, oh Má gbẹsẹ́ lọkánkán o, ní méjì-méjì Áà tí b'orí ọfọ àti ìbànújẹ́, hmm Máà mì bo wùn o oh Ààní boo fẹ d'oókòtò Ah, gbogbo wá là wá níbẹ, là wá níbẹ Gbogbo wá là wá níbẹ, po! (L'agbo onidẹra) gbogbo wá là to debẹ, ey A pọ níbẹ', gbogbo wá là wá níbẹ, po! Má gbẹsẹ́ lọkánkán o, ní méjì-méjì Áà tí b'orí ọfọ àti ìbànújẹ́, ohh Máà mì bo wùn o oh Ààní boo fẹ d'oókòtò Ehn? Gbogbo wá là wá níbẹ, ehh, à wá níbẹ Gbogbo wá là wá níbẹ, po! (L'agbo onidẹra) gbogbo wá là to debẹ, bẹẹni A pọ níbẹ', gbogbo wá là wá níbẹ, po! ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ehn, ṣé b'áwọ lo l'érè òní ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo o ẸniỌbankẹ (ìtànṣán oòrùn) ehn, ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o Woah-oh-oh, kà lọ, kà jọ débẹ o, yea, oh-oh ẸniỌbankẹ Itàna ọdẹdẹ Itànṣán oòrùn Atọnìsọna