Mò ń lọ l'óko, mi ò mà l'ẹ'nìkankan Mò ń w'ọ'nà f'ára mi Mò ń là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ' Mò nṣè'wọn tí mo lè ṣe Bí mo bá ń bọ' l'óde, ma ṣè'bà f'ágbàgbà E mi ò dè'nà m'ẹ'nìkankan Mò ń w'ọ'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ' Mò nṣè'wọn tí mo lè ṣe Kí'lé ayé wa dùn k'ó l'áyọ' K'a ṣè'wọn t'a lè ṣe K'a fì iyókù sí'lẹ' K'a là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ' K'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o (Ayọ̀, idẹra) k'a j'èrè ìbàlẹ' ọkàn, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o (Ah-aah, ayọ' idera) k'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o (Ah-ayọ', idẹra) k'a j'èrè ìbàlẹ' ọkàn, pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ' o (Ah-aah, ayọ' idẹra) Ẹgbẹ' oníre l'àwa ń bá rìn Àwa ò gbìmọ' àdánìkanjẹ À ngbèrò k'ó lè da o A mí ṣè'tò kí aṣálẹ' k'ó dì ilú olóyin Ẹ jẹ' a gbé'ra ní'lẹ', k'á má ṣ'ọ'lẹ K'a ṣè'wọn t'a lè ṣe K'a fì iyókù sí'lẹ' K'a là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ' K'a lè j'ogún ìdẹ'ra pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o (Ah-aah, ayọ̀ idera) k'a j'èrè ìbàlẹ' okàn pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ' o (Ah-aah, ayọ̀ idẹra) k'a lè j'ogún ìmolẹ' tí bo'rí òkùnkùn biri Mò ń lọ l'óko, mi ò mà l'ẹ'nìkankan Mò nw'ọ'nà f'ára mi Mò ń là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ' Mò ń ṣè'wọ'n tí mo lè ṣe o Bí mo bá ń bọ' l'óde, ma ṣè'bà f'ágbàgbà E mi ò dè'nà m'ẹ'nìkankan Mò ń w'ọ'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ' Mò ń ṣè'wọ'n tí mo lè ṣe Kí'lé ayé wa dùn, k'ó l'áyọ K'a ṣè'wọ'n t'a lè ṣe K'a fì iyókù sí'lẹ' K'a là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ K'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o (Ayọ̀, idẹra) k'a j'èrè ìbàlẹ' ọkàn, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o (Ah-aah, ayọ̀ idẹra) k'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ' o (Ah-ayọ̀, idẹra) k'a j'èrè ìbàlẹ' ọkàn, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o (Ah-aah, ayọ' idẹra) k'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o (Ah-aah, ayọ' idẹra) k'a lè j'ogún ìmolẹ' tí bo'rí òkùnkùn biri (Ah-aah, ayọ' idẹra) Pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ' (ah-aah, ayọ' idẹra) (ah-aah, ayọ' idera) pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ (ah-aah, ayọ' idẹra) (ah-aah, ayọ' idẹra) pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ (Ah-aah, ayọ' idẹra) (Ah-aah, ayọ' idẹra)