Cifra Club

Formation (feat. Olamide)

Adekunle Gold

Aún no tenemos los acordes de esta canción.

All my ladies, formation
All my ladies, e jale
Form', form', forma'

All my ladies formation, if you are sexy, go low, low (low, low)
Fine bọbọ, wetin sup? If you want it, you lowo (lowo)
Fuck with me, baby, don't let me go (me go)
Stop it, don't call me, Bro
Ewo l'ewo sisi eko, baby, hello
She say: Oh, my Lord
Talk is cheap, show me working
Ah, ṣo n te button, ko le re body

Ẹ pé money changer kò ṣe'wo
Electro-fuji ló fẹ́ Jó
Palazzo we ṣe ẹ máa gbọ́
Bureau de change, Kwankwanso
Ẹ pé money changer kò ṣe'wo
Kosoko music ló fẹ́ Jó
Palazzo we se ẹ máa gbo
Bureau de change, Kwankwanso

Ayy, fi le bẹ (ah, ah), jo wa be
Ẹ jẹ́ kó lọ bẹ, wọn fẹ́ mọ bí mo ṣe jẹ́
Ọmọ iya mi, no dey vex
Ẹ sọ fún kó stop, ṣe be? (Yeah)
Ọmọlọmọ wọn níbọ ló ti r'ọwọ náà? '
Ìṣẹ́ kékeré, owo nla nla (nla, nla)

Wọn lè wọn lè, wọn lè bá
(Dey with me) wọn lè bá

Million, million dollar, ló na dollar
No be small, small, dollar
No be young young dollar, tan na dollar, awọn young dollar
Three comma, comma, lo gbe comma, owo Otedola
Stay close to me, my baby, you-I gate to Mokola
Olólùfẹ́ mi baby (uh), ìwọ ṣà má ready (uh)
Whenever you ready (uh), kí ìwọ ṣa ti pè mí (uh)
Anything to ba fẹ, bó jo ku lo o láàlé
To ba ja cover ló fẹ́, ma ṣa nà sí lẹ labe, labe, labe

Ẹ pé money changer kò ṣe'wo
Electro-fuji ló ń fẹ́ Jó
Palazzo we ṣe ẹ máa gbọ́
Bureau de change, Kwankwanso
Ẹ pé money changer kò ṣe'wo (ẹ̀ pé money changer)
Kosoko music ló ń fẹ́ Jó (oh, money spender)
Palazzo we ṣe ẹ máa gbo (baby, ta la so)
Bureau de–, Kwankwanso

Ayy, fi le bẹ (ah, ah), jo wa be
Ẹ jẹ́ kó lọ bẹ, wọn fẹ́ mọ bí mo ṣe jẹ́
Ọmọ iya mi, no dey vex
Ẹ sọ fún kó stop, ṣe be? (Yeah)
Ọmọlọmọ wọn níbọ ló ti r'ọwọ náà? '
Ìṣẹ́ kékeré, owo nla nla (nla, nla)

Otros videos de esta canción
    0 visualizaciones

    Afinación de los acordes

    Afinador en línea

    Ops (: Contenido disponible solo en portugués.
    OK