All my ladies, formation All my ladies, e jale Form', form', forma' All my ladies formation, if you are sexy, go low, low (low, low) Fine bọbọ, wetin sup? If you want it, you lowo (lowo) Fuck with me, baby, don't let me go (me go) Stop it, don't call me, Bro Ewo l'ewo sisi eko, baby, hello She say: Oh, my Lord Talk is cheap, show me working Ah, ṣo n te button, ko le re body Ẹ pé money changer kò ṣe'wo Electro-fuji ló fẹ́ Jó Palazzo we ṣe ẹ máa gbọ́ Bureau de change, Kwankwanso Ẹ pé money changer kò ṣe'wo Kosoko music ló fẹ́ Jó Palazzo we se ẹ máa gbo Bureau de change, Kwankwanso Ayy, fi le bẹ (ah, ah), jo wa be Ẹ jẹ́ kó lọ bẹ, wọn fẹ́ mọ bí mo ṣe jẹ́ Ọmọ iya mi, no dey vex Ẹ sọ fún kó stop, ṣe be? (Yeah) Ọmọlọmọ wọn níbọ ló ti r'ọwọ náà? ' Ìṣẹ́ kékeré, owo nla nla (nla, nla) Wọn lè wọn lè, wọn lè bá (Dey with me) wọn lè bá Million, million dollar, ló na dollar No be small, small, dollar No be young young dollar, tan na dollar, awọn young dollar Three comma, comma, lo gbe comma, owo Otedola Stay close to me, my baby, you-I gate to Mokola Olólùfẹ́ mi baby (uh), ìwọ ṣà má ready (uh) Whenever you ready (uh), kí ìwọ ṣa ti pè mí (uh) Anything to ba fẹ, bó jo ku lo o láàlé To ba ja cover ló fẹ́, ma ṣa nà sí lẹ labe, labe, labe Ẹ pé money changer kò ṣe'wo Electro-fuji ló ń fẹ́ Jó Palazzo we ṣe ẹ máa gbọ́ Bureau de change, Kwankwanso Ẹ pé money changer kò ṣe'wo (ẹ̀ pé money changer) Kosoko music ló ń fẹ́ Jó (oh, money spender) Palazzo we ṣe ẹ máa gbo (baby, ta la so) Bureau de–, Kwankwanso Ayy, fi le bẹ (ah, ah), jo wa be Ẹ jẹ́ kó lọ bẹ, wọn fẹ́ mọ bí mo ṣe jẹ́ Ọmọ iya mi, no dey vex Ẹ sọ fún kó stop, ṣe be? (Yeah) Ọmọlọmọ wọn níbọ ló ti r'ọwọ náà? ' Ìṣẹ́ kékeré, owo nla nla (nla, nla)