BREAKFAST

Qdot

    Continúa después del anuncio

    (Lílù)
    Alágbe (Shocker lo ṣe beat)
    Onílù yí jọ- oo
    Ọmọ ẹluku mẹdẹ-mẹdẹ, ìmolè àfelẹja
    Emi naní, ọmọ-ọmọ Moriamo
    Qdot l'orúkọ kọ mí

    Wọni oro dákun mà soko, ẹjẹ ńsọ tọwọ mí náà
    Ẹdakún, níbo lo wa, nígbà tí mo fojú wina?
    Mo badi, ìmolè ní mí
    Òyìnbó odún lẹnu mí, torí Ìbílẹ ní mí
    Tẹ ba ní ké mú ẹnì àf'ọlá
    Labalaba tó ṣẹré ẹ̀gún, aṣọ rẹ mafaya

    I'm here for the money, not the fame
    Ask about me, I'm making money in the game
    B'ologiní bà gún orí ajá, àrí'lé àrọko
    Fuck anybody fuckable, I don't care
    Mo dá bí Messi, mo dá bí C'Ronaldo
    Mo mọ Sanwo Ayanlu, ẹruku mo bá tó

    Lalude gàn o'lẹ p'Abija
    Ọmọ Ìbàdàn tó f'èwe sẹnu, ṣọ'le Bodija?
    Ẹtakete, berí mí ní orítá Molete, emí kó lé má challenge
    Moda, (moda gan)
    Àta ní mí, motá (mota gan)
    Ìná mí o mẹní tó da, werepe ní mí, ẹma loja

    Continúa después del anuncio

    (Alagbe sọrọ)
    Award onigi, iná ìgi lama fí dá
    Fuck your lyrics, he's on the road, I'm the best
    Tába tí àdà, fún àwọn tìwá wọn o dá
    Wọni wọn ogbọmí, speaker wọn ní o dá
    Mí o need akaba, kí ńto ga t'àlaga
    Ká dobalè fún àrá, ìyẹn o ní kamá ga

    Punchline fọ wọn lẹ'nu lọ gba-gba-gba
    Ẹsẹ' May Weather mo gbéwá
    Dákun, mà lọ faya gbà
    Ayangba dangerous
    Makinde pá'wó ju Linda Ikeji lọ
    Ẹma pá ohùn má gogo, ẹjẹ ń polongo

    Ẹṣù lo lorita, Oluweri lo lodò
    Don't near me, I'm bad
    Ọmọ àke nígbo, keru bá àrá ọna
    Ọmọ má jegi jẹ èniyàn, oríkì Bàbá mí ní
    Oka mí lará gàn, o'sho jù Abu Abel
    Ṣebi ká rín, kápọ, yíyẹ ní ńyẹni
    Ko dẹ ní yẹ yín, ewúré lo má gbà ògo yín

    Boku ọwọ kàn àdán, àdán má fí rogi
    Kólé burú títí, kí ọmọ àlapatá mí wá jegi
    Wọn wípé mariwo larí, pe'égún ńbọ
    Nígbà tẹ'gún rí wá gàn, eégún gbọn
    Ẹdakún, ṣẹ'ẹyẹ àdán ní (àbí) ẹiyẹ guungún?
    Wọni àwọn m'ẹyẹ lápo, ẹiyẹ tún tí kú
    Bà rán niṣẹ ẹru, àmà fí tọmọ jẹ
    Bàbálawo tí o já, lomá padà toro jẹ
    Bí ìṣe kàn o lomọ, ìṣẹ kàn lo ńlọ

    Tí o bá jawó lo rí dating, gbé sórí PPP
    Wọni, Acapella rẹ dùn, ìwọ dákun má fí ìlù sí (Shocker lo ṣe beat)
    Saladi mí, lọ fẹ bámí fí ìru sí
    Ogún tí o jẹ, ṣẹ bí ẹwé ẹ loku kàn
    Ọba ní mí Alagbe o rẹ bí kán-kán

    Kabiesi o (kabiesi o, kabiesi o) (yeah, who's here?)
    Ọmọ Àjànà

    Información de la canción

    Composición:

    ¿Los datos están equivocados?

    Enviar revisión