Ewe

Qdot

    Continúa después del anuncio

    Petrol hydro canabino

    Ewé dùn, lebe-lebe le oh, (ewé)
    Lebe-lebe-lebe-lebe oh
    Ewé dùn (ewé oh)
    Lebe-lebe le oh (ewé oh)

    Tórí, tèmi bà r'ewe inú mí à dùn (ayy)
    Ará mí à ya ga-ga oh (ewé dùn)
    Làtete kòṣe Bàbá tí d'ewe
    Ewé ọlá, ewé àlàáfíà
    Ewé mà múní l'aradà
    Ewé dá f'àgbàlagbà, ewé dá fún àwọn ewé

    Ewé dùn bí omidùn
    Ẹ'fọ' ugwu, no be kanaku
    Ó yatọ s'ewe ewedu
    O yatọ s'ewe akoko

    Bàbá, ìwọ ló ń d'ewe f'awa èwe
    Ó ní k'aja lóko, k'asa k'ọgbẹ́, kà we laṣọ, kà f'ina sí
    Ibà f'àwọn ọmọ mí èwelé
    Eléwé ń j'ewe, wọn j'ewe lọ (ewé)
    Pé ìlú ódà, ìlú ódà, wọn f'ewe ṣàyé lọ (f'ewe ṣàyé lọ)
    Qdot lórúkọ mí (ewé oh)

    Continúa después del anuncio

    Ẹ fún mí ní ewé oh
    Ewé ọ'la, ewé àlàáfíà
    Ẹ bámí we ewé oh
    B'ina yẹn ó lekú, tí ń báti rí kanaku
    Ẹ fún mí ni ewé oh
    Ewé ọlá, ewé àlàáfíà
    Ẹ bámí we ewé oh
    B'ina yen o leku, tí ń báti rí kanaku

    You fit turn in the ghetto if in your eye
    If your brain no strong, broda, run away (away)
    Kòṣe fí s'ara kú, ma ṣ'afara we (ewé oh)
    Ọlọrun mí ga, ẹ'mí náà à ga, tí ńba tí gbé'wé lu'ra

    Rọra ṣé oh, rọra ṣe
    Ọmọ ẹ'mí, rọra ṣe
    I believe I can fly (higher)
    Òní cigar fọ f'onigbo
    Onigbo ń fọ fún ele 'S.K oh
    S.K ń fọ fún paw-paw oh
    Paw-paw padà fọ fún Arizona oh
    Arizona, padà fọ fún Loud oh

    Pé ta'loni Loud fọ fún Colorado (e yayy-yy, e yayy-yayy) (ma we)
    Lat'ete kòṣe ní ewé tí wá (mà we)
    Baba lódá ewé pẹ'lú egbò (mà we)
    Òun t'Ọlọrun dá, dára-dára ni (mà we)

    Kólé yí wá lórí oh (mà we)
    Ó ma ń wú mí lórí oh (mà we)
    Erúku Elegusi tóni iru (mà we)
    Tófi dé Ikeja lọ'dọ' Baba Fela (mà we)

    Àwọn tèmi l'Oniru oh (ma we)
    Dé aládùúgbò, wọnú Laketu (ma we)
    Ita Aro, àyé ò pare (ma we)
    Nísàlẹ̀, mà dé down, down, down (ma we)
    Lẹgbẹ church àwọn mummy mí (ma we)
    K Sir Sosse no dey smoke the kpoly (ma we)

    Shout out to Baddy Ooshaa (ma we)
    Shout out to Lanre Typical (ma we)
    Milli Hustle, ọmọ Salawe (ma we)
    Xsmile, f'arabale báń yí (ma we)
    Málọ gb'oja wọ Dubai (ma we)

    (Yeah, who's here?)
    Ah, fire burn the wicked
    Àwọn toni k'ama mú igbo weekend

    Información de la canción

    Composición:

    ¿Los datos están equivocados?

    Enviar revisión