Gbeja (feat. Pasuma)

Qdot

    Continúa después del anuncio

    Pasuma wonder oh
    Ìjọba Fuji oh
    Bàbá Wasila
    Daddy Rokiba

    Qdot lórúkọ mí
    (2T upon deebeatz)
    Kòye wọn

    Wọn fẹ mọ'di abájọ mí
    Wọn fẹ mọ'lé bàbá alájọ mí
    Ọtá fẹ mọ ìgi lẹ'yìn ogba mí
    Wọn fẹ mọ'ye t'ówà ní ipamọ mí oh
    Bàbá mí lókè ńpá mí mọ

    Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Àdúrà lo ń gbà, àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Oṣó ń gb'ogun, ọ'tá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)

    Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
    Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
    Ìṣẹdà mí, gbéjà mí jà (gbéjà)
    Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)

    Ẹ jẹ kà dúpẹ' pé ènìyàn kò ló l'Ọlọrun wá
    Kà lènìyàn ní, ènìyàn lé ní k'òjò má ro, sùgbọn
    Àdúrà lógbà, àyé fẹ pá kádàrá mí dá, ṣùgbọn
    Kín má wọ jersey, kín má wọ bootu
    Penalty mí ó lé jẹ'rín

    Continúa después del anuncio

    Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Àdúrà lo ń gbà, àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)

    Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
    Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
    Ìṣẹdà mí, gbéjà mí jà (gbéjà)
    Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)

    Èmi lẹni t'ayé tí ro (t'ayé tí ròpìn oh)
    Pé kólé dá ń kán 're ṣé o ('re ṣé o)
    Ṣùgbọn, mó rí àánú ẹ gbà, Olú Ọ̀run o, lo bamiṣé oh (Alabi oh)
    Wọn sáré, sáré, sáré
    Olúwa júwọn lọ
    Wọn gb'ero pé kó bàjẹ́ ní, orí mí ó gbàbọdé o (Paso)

    Wọn rò p'ótàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Àdúrà lo ń gbà àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)

    Orí wá, gbéjà fún mí já oh (gbéjà)
    Orí mí, Jáà fún mí (gbéjà)
    Ìṣẹdà mí gbéjà mí jà (gbéjà)
    Dàkún, wá jà fún mí (gbéjà)

    Bàbá mí tí ṣé, Bàbá mí tí ṣé, Bàbá tí ṣé
    Oùn t'aye rope kò ṣé-ṣé, Abaniṣe tí bámí ṣé
    Òun tímo wá lọ Sokoto, o ń bẹ l'apo ṣòkòtò mí
    Ọmọ tóní kólé pa'gan, ó ko'lé alarinrin

    Àdúrà lógbà (àdúrà lógbà)
    Àyé fẹ pá kádàrá mí dá, ṣùgbọn
    Kín má wọ jersey, kín má wọ bootu
    Penalty mí ó lé jẹ'rín

    Wọn fẹ mọ'di abájọ mí (mọ'di abájọ mí)
    Wọn fẹ mọ'lé bàbá alájọ mí (bàbá alájọ mí)
    Ọtá fẹ mọ ìgi lẹ'yìn ogba mí
    Wọn fẹ mọ'ye t'ówà ní ipamọ mí oh
    Bàbá mí lókè ńpá mí mọ

    Wọn rò pé ó tàn fún ọmọ ológo (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Àdúrà lo ń gbà àgbàrá kọ (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Ìbí léké-léké tí ń fo'ṣọ, kos'ẹyẹ tó mó bẹ oh (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)
    Oṣó ń gb'ogun, ọtá ń gb'ogun (Bàbá mí lókè ńpá mí mọ)

    Información de la canción

    Composición:

    ¿Los datos están equivocados?

    Enviar revisión