Idan

Qdot

    Continúa después del anuncio

    Qudusi idán (2t upon the beats)
    Idán gangan, idán
    Ọmọ Mọriamọ, idán (idán o-o)
    Qdot l'orúkọ mí

    Wọn mòpé emi ni idán (idán)
    Idán tí ó wẹ tó ń dán (idan)
    Qudusi idán (idán)
    Idán kí dàn (idán)
    Báwo l'áyán Lekki ṣé ń dan? (Idán)
    Àdánwò o kin ńse ọrẹ idán (idán)
    Gbowó lọwọ Palmpay (idán)
    Ko fi sanwó Opay (idán)

    Idán o gbọdọ sùn (idán)
    Tori Yanki o ni pẹ ji (idán)
    Owó olówó l'égún na (idán)
    Ootọ ni Peller ńpá dan (idán)
    Obesere lóhùn lọ Ọba idán (idán)
    Sugbọn, idán gangan lonju idán (idán)
    Oùn lomu Sọdiki ọgbọnn (idán)
    Gan lọ gbà arodan fún dan (idán)

    Ẹ wọn mì sì tàn omidan (idán)
    Kẹ to gbé tan le tan (idán)
    Ẹma jẹ dan mọ dan (idán)
    Ki idán ma ṣẹrù fún omidan (idán)
    Idán wey slap popo (idán)
    Idán no dey sleep (idán)
    Na sleep dey wait for idán (idán)
    Idán òní wówó kiri (idán)
    Owó ló má ń wa 'dán (idán)

    Idán na him be the don (idán)
    Na why idán dey sit down (idán)
    Alhamdulillah (idán)
    Mo mọpé ẹ ti jẹ yẹn tán (idán)
    Ọlá Olùwà o kín tán (idán)
    Lamba mi o le tán (idán)
    Kàkà ki idán jabọ sí kòtò (idán)
    Mọnamọna ma tàn (idán)

    Continúa después del anuncio

    Idán na don (idán)
    Idán na high don (idán)
    Don Jazzy gan bẹ'rù idan (idán)
    Wọle Soyinka tio bẹ ru idán ni
    Ori ẹ ma dán (idán)
    Adan bi t'ogidan (idán)
    New Edition, idán (idán)
    Fẹnu ro dan (idán)
    Fẹnu wù igi odán (idán)

    Ma ba wọn fẹnu lu gángan (idán)
    Ma wo ojú ko tọ fẹnu jù 'dan (idán)
    Idan ju 'dan lọ (idán)
    Loni yan-yan, yan-yan, yan
    Olè sọrọ, online lowa (idán)
    Chicken, ò lè fò bi ẹyẹ àdán (idán)
    Eku ni ifá ńjẹ (idán)
    Adífá lonjẹ màlúù (idán)

    Idan no be yahoo (idán)
    Idán to ń dàn (idán)
    From Bourdilon to Aso Rock (idán)
    Jagabanu ní idan (idán)
    Mo mọ awọn idán gangan
    IBD Dende, idán
    Ọmọ Egungbohun, idán
    Ṣeyi Tinubu, idán
    Baddy Osha idán

    Lanre Typical, idán
    Kosi idán kàn ton tá mọto
    Lẹyìn Arowolo, idán
    MC Oluọmọ, idán
    Riliwanu Cooler, idán
    Ọba Sheffield, idán
    Kunle Poly, idán
    Tafa Sego, idán
    Kazeemu Elesu, idán

    Kapa Owoẹyẹ, idán
    Ọkanlọmọ, idán
    Ajibola Pasuma, idán
    Mo mọ Fẹmi Joro, mo mọ Fẹmi Jaguar
    Abu Abel, idán
    Sammy Larry, idán
    Tarry Shiny, idán
    Anọbi tiwa ni Mushin
    Mo mọ Lawali l'Abuja

    Mo ṣe bà Oníbà of Ibà
    Billique, idán
    Maverick, idán
    Doctor Brown, idán
    Bobrito, idán
    Mo mọ Wale ticket
    Kazzy lo fi idán sí mọto
    Eniola Tizzle, idán
    Ọlọfin Snipper, idán

    Ẹgbọn mi Bunmi Obakoya
    Tunla of Lagos, idán
    Mo mọ Bishop nílù Turkey
    Mo mọ Dandy, mo mọ Otunba Kashy
    Ọmọ Ayilara mi, ọrọ pọ Ọmọba Kumasi
    Ikorodu wa, say boko, Alabi Spatarcuz

    Baba Rado, Qdot l'oruko mi
    2T upon the popo o-o
    (2T on the mix)

    Información de la canción

    Composición:

    ¿Los datos están equivocados?

    Enviar revisión