Moriamo

Qdot

    Continues after the ad

    Ọmọ Adefi
    Ọmọ Adefa lókè Iresi
    (Moriamo Alege) (Moriamo)

    Ìyá bàbá mí, sún re
    Ní ilé àyé, 1980 something (The Beat Handle)
    Damilare, èmi l'àkọ́bí bàa mi, kí Qudus tó dì Qdot
    Ìyá àti bàbá mí tí Jáà ó tí pẹ
    Kín tó wa'yé lótí ní wọn le fẹ'ra wọn
    Okun ẹbí t'oba Jáà, welder kàn ó lé jo (Alagbe)

    K'Ọlọrun f'ọrun kẹ Moriamo, ìyá bàbá mí
    Moriamo, ọmọ Alege
    Ìyá má ń gb'ọmọ gẹ-gẹ ní
    Màmá ó gbé mí sílẹ̀ k'èyàn kan-kan tọju mí
    Moriamo, ọrun re
    Mí ó gbàgbé okò Alado o, l'ọnà Erugbabu
    Okò obi yí grandma tí fọ lójú kàn
    Bóyà ń torí obi tó mà tá ní muri kàn

    Ìyá yí tún padà s'oko, ada, t'ohun t'ọkọ ní
    Orí mí à wú to bà pé mí lọkọ' mí
    Ọjọ rí jẹ, pẹlú ọjọ rírí mú
    Màmá ma ń r'oka pẹlú ẹfọ Bọkọlu

    Omi odò là má ń mú (omi odò là má ń mú)
    Labúlé Ado, labúlé Ado oh (labúlé Ado)
    (Abúlé Ado) abúlé wá ó jìnà si Shagamu
    À ńpadà s'oko ní motor jamu (ó má ṣée)
    Màmá bà ń pariwo: Damilare, ọmọlọmọ ní, ẹ bà ń gbé
    Ó mà ṣeé, ó mà ṣee (ó mà ṣeé)
    Ọjọ yẹn ní mo mọ pé ìyá yí kọ lo bí mí

    Moriamo Alege (Moriamo)
    Moriamo Alege (Moria oh)
    Moriamo Alege, ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ

    Continues after the ad

    Moriamo Alege (Moriamo)
    Moriamo Alege (Moria oh)
    Moriamo Alege
    Ìyá bàbá mí, ọrun rè rẹ (Moriamo)
    Ọrun re rẹ (Moria oh)

    Hmm, ọjọ re bí ana nígbà t'ikú wọlé dé
    Ìyá yí tí r'ikú lóṣe ní ń b'ode lọ
    K'ojú mí mà bà r'ibi
    Rafiu, àbúrò mí ń gbà bọọlu nítá
    Mo wọlé padà, màmá tí d'ojú bo'lẹ

    Kàyéfì lójẹ', mo sáré pé bàbá mí
    Adio, ó bà dákún, wá wó màmá rẹ
    À ṣé ọlọjọ lódé o
    Ńgbà t'ariwo tá, lo ńbí wà, Kílódé?
    Kín to mọ, ẹsẹ tí pé
    Shifau, pẹ'lú Mutairu béèrè sí ńké (omijé oh)

    Wọn ní wọn ó le sìn màmá
    Moní, Kílódé?
    Wọn ní, Ẹmí ó jáde tán (ahh)
    Kòfẹ fimí silẹ lọ ní
    Ọjọ ìkíni lọ, ìkejì lọ
    Ọjọ ìkẹta, Moria dágbere fún'ayé

    Moriamo Alege (Moriamo)
    Moriamo Alege (Moria oh)
    Moriamo Alege
    Ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ

    Moriamo Alege (Moriamo)
    Moriamo Alege (Moriamo)
    Moriamo Alege
    Ìyá bàbá mí, ọrun re rẹ (Moriamo)
    Ọrun re rẹ (Moriamo oh)

    Moria dàgbere fún ayé
    Odi'gbà, odi'gbere (Moriamo)
    Mama Shifau, Mama Mutairu
    Moriamo, ọmọ Alege, ọrun re rẹ

    Mà ro'yin ẹ f'ọmọ mí (Moriamo oh)
    Moriamo (Moriamo), Moriamo oh
    Moriamo (Moriamo)
    Moriamo Alege

    Yeah, who's here?

    Song details

    Composition:

    Did you see an error?

    Enviar revisão