Olopa (feat. Qdot)

Zlatan

    Continúa después del anuncio

    (Yeah) Ìbílẹ'
    (Yeah) kapaichumarimarichopaco

    (Qdot lórúkọ mi) Alagbe, jẹ ọ mọ
    Ṣo ńgbọ? Ko sodi mare, wèrè loku (yepa)
    (Gun òkè) wọn ká pátá lọ tokun-tokun (ẹ da'gbo rú, jọọ)

    Ẹ p'ọlọ́pàá (ẹ pé ọlọ́pàá)
    Ẹ pé soldier (ah, ẹ pé soldier)
    Ẹ lọ pé EFCC, tó bá dé'bi, à jọ má ṣáyé pọ
    Ayé toto (ayé toto)
    Ayé akamara (ah, ayé akamara)
    iPhone lo ko'wo le, ọmọ ase, fufu lo ra (hello ẹ)

    Ẹ dàkún, ẹ gbàmí, fufu lora oh, o san'wó miliki kuunu ló gbà oh
    Kórà Benz, katapupu lora oh
    Af'ọwọ fa lekute, to jẹun tàn toni k'ologbo wà wo òun
    Àwọn ẹni lọ, lobọ nìkan lo le sọ nípa ọlọdẹ Abuja
    Tofa coro' lẹ yìn bọn s'ọmọ aja
    B'ìṣù ẹnì bàtá, f'ọwọ bojẹ
    T'oba ta yama-yama, d'aṣọ bojẹ
    Ṣùgbọ'n, ẹní a wí fún, Ọba, jẹ ò gbọ
    Airpod iPhone ní òní jẹ ò gbọ

    Ẹbí wọn, kilode?
    Torí mo ji lapi, 'bọn na wọn ní mo ja wọn ní wire ni Ìbàdàn, ah-ah
    A ba'tan, a ba'rọba pé òyìnbó tí kowa lẹ́rù nígbàkàn (yeah)

    Continúa después del anuncio

    Ẹ pé ọlọ́pàá (ẹ pé ọlọ́pàá)
    Ẹ pé soldier (ah, ẹ pé soldier)
    Ẹ lọ pé EFCC, toba débi, à jọ má ṣáyé pọ (yayy) (à jọ má ṣáyé pọ)
    Ayé toto (ayé toto)
    Ayé akamara (ayé akamara)
    iPhone lo ko'wó le, ọmọ ase, fufu lora (hello ẹ)

    Ahn-ahn, kúròńbẹ
    Ò mọ commissioner (ò mọ commissioner)
    Ye, òtún mọ Buhari (ha, ò mọ Buhari)
    Ah, otí rí ọmọ gọ
    Ọmọ àse ti'odẹ tún mú garri rí (ti'odẹ tún mú garri rí) (kúròńbẹ)
    Ghetto mo gbè dàgbà, ẹ le p'àjà fún mí lọbọ, Broda Laja (ah, Broda Laja)
    Ọrọ mí tí d'aleba, kole já tẹbá fa, double seat yin leja (kúròńbẹ) (ahh, okolo)

    Èmi para-para, wọn lé wojù mí, wọn tún le bami ta'ka (wọn tún le bami ta'ka)
    Ẹ fẹ pàwọn, taló lọ ń fix Eyimba pẹ'lú Barca? (Pẹ'lú Barca)
    Kúròńbẹ, mo wọlé, game dẹ change
    Mora motor lọwọ IVD, mi ò tún gbà change (ẹ gbàgbé ẹ)
    Abínibí yàtọ' sí ability (yeah)
    Wọn ja'jakadi, kò dẹ gbàgìdi (o pọ)

    Ẹ pé ọlọ́pàá (ẹ pé ọlọ́pàá)
    Ẹ pé soldier (ah, ẹ pé soldier)
    Ẹ lọ pé EFCC, tó bá dé'bi, à jọ má ṣáyé pọ (à jọ má ṣáyé pọ)
    Ayé toto (ayé toto)
    Ayé akamara (ah, ayé akamara)
    iPhone lo ko'wo le
    Ọmọ ase, fufu lo ra (ahn, ahn, yea)

    Kọnga ṣálanga ma ńji jùra lọ
    Àrà l'ama tí mọ, t'aba jẹun j'ara lọ
    Àwọn sọlo Makinde, ṣọbọlọyọke
    Àwọn wèrè, wọn fẹ mọ ìbí t'ati bádé
    Lapa-lapa mú wọn l'ọpọlọ
    Ó yá wọn lẹ'nu bí moṣe ńjẹ lọ

    I'm making money with my tonation
    Awọn ní àwọn fẹ ṣé investigation
    I say, " The rhythm moment song tó fantastic
    Ata di ẹ mo fí sí, t'owa fantasy "
    Dem say I too dey speak Yorùbá
    I'm sorry, I no be Calabar

    Wọn ni mo ji lapi, 'bọn na mo fí mo ja wọn ní wire ni Ìbàdàn (yeah)
    A ba'tan, a ba'roba pe òyìnbó tí kowa lẹ́rù nígbàkàn

    Ẹ pé ọlọ́pàá (ẹ pé ọlọ́pàá)
    Ẹ pé soldier (ah, ẹ pé soldier)
    Ẹ lọ pé EFCC, tó bá dé'bi, à jọ má ṣáyé pọ
    Ayé toto (ayé toto)
    Ayé akamara (ah, ayé akamara)
    iPhone lo ko'wole, ọmọ ase, fufu lora (ahn, ahn) (fufu lora) (yeah)

    (Kúròńbẹ)
    Yeah
    Yeah, who's there?
    Yeah
    Yeah
    Yeah
    Yeah
    Yeah
    Yeah

    Información de la canción

    Composición:

    ¿Los datos están equivocados?

    Enviar revisión