Omo Ologo

Zlatan

    Continúa después del anuncio

    Till the second coming of Jesus Christ, I go dey give them
    Mo t’ajero from Monday till Friday, jaiye ni weekend
    I don’t need up to sixteen bars to prove that I am wicked
    And I bet you all can testify that this young nigga is gifted
    Oya wọn lẹnu bi mo shey tana tan seventeen eighteen nineteen
    Best act AFRIMMA, la ba gboriwo quarantine
    Lockdown fẹ run wa down, la ba fariga fara ki
    Ki lọn ma gain ti n ba fall
    Tẹ ba r'ota mi, ẹ bami bi

    Kuonbe!
    Lamba yapa oloungbo walahitalahi (Walahitalahi)
    God dey bless me too much me I no deny (No dey)
    And that’s why they all chasing when i’m driving by (Skrr, skrr)
    I pray make my Samson no ever meet Delilah

    See
    Symbol of hope
    For their eye e be like soap
    Wọn fẹ ki n ma fayawọ bi crocodile aṣọ Lacoste
    O wa lara mi, o kun se, o tun sẹ danu
    Fun eyin tẹ komije, tẹ n gbọn mi mu, ẹ o ni ridamu

    Kuonbe!
    Ọmọ trenches ninu Lamborghini
    VVS lọrun. Jaiye n Santorini
    Aṣọ Gucci, sokoto Amiri
    Toba shele wa mo pe ẹsha ni Richard Mille

    Continúa después del anuncio

    Ọmọ Ologo!
    To ba ti rimi, o rọmọ ologo
    Ọmọ Ologo!
    To ba ti rimi, o rọmọ ologo
    Ọmọ Ologo!
    To ba ti rimi, o rọmọ ologo
    Ọmọ Ologo!
    To ba ti rimi, o rọmọ ologo

    Kuonbe sẹ
    Stack the money up, stack the money up owo lo shey igboro (Kilowi?)
    Rale fun mummy, ra fun daddy, maje k'owo s'ojoro (Kilosọ?)
    Tẹ pa mo sẹ, ni maga
    O di dandan ẹsẹ a gun (Jenmọ)
    Oma sisẹ, oma laagun (Jenmọ)
    O de le sọ aagun di'gbadun
    E no matter how the background dey be
    O le di arabanbi, o le sọ bye-bye si garri
    All man for himself, oju lari
    Bọrọ yi shey n bayin, bẹẹ na lo n bamiwi (Kiloso?)

    Ọmọ trenches ninu Lamborghini (Lambo)
    VVS lọrun, jaiye Santorini
    Asọ Gucci, sokoto Amiri
    Toba shele wa mo pe esha ni Richard Mille (Esha)

    Ọmọ Ologo!
    To ba ti rimi, o rọmọ ologo
    Ọmọ Ologo!
    To ba ti rimi, o rọmọ ologo
    Ọmọ Ologo!
    To ba ti rimi, o rọmọ ologo
    Ọmọ Ologo!
    To ba ti rimi, o rọmọ ologo

    Kuonbe sẹ
    Stack the money up, stack the money up owo lo shey igboro (Kilowi?)
    Rale fun mummy, ra fun daddy, majẹ k'owo s'ojoro (Kilosọ?)
    Tẹ pa mo sẹ, ni maga
    O di dandan ẹsẹ a gun
    Oma sisẹ, oma laagun
    O de le sọ aagun di'gbadun

    Información de la canción

    Composición: Zlatan

    ¿Los datos están equivocados?

    Enviar revisión