Cifra Club

Oxalá

Majur

Aún no tenemos los acordes de esta canción.

Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà
Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà
Elémoṣọ̀ bàbá Ológun
Ajagunà gbà àwọ̀

Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà
Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà
Elémoṣọ̀ bàbá Ológun
Ajagunà gbà àwọ̀

Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà
Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà
Elémoṣọ̀ bàbá Ológun
Ajagunà gbà àwọ̀

Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà
Ajagunà gbà àwọ̀, Ajagunà
Elémoṣọ̀ bàbá Ológun
Ajagunà gbà àwọ̀

Ò fúrùrú lóòréré o
Àìláà Bàbá kényènyè ní Ejìgbò
Ilé Ìfọ̀n mo ti wá, Bàbá
Ejìgbò rere, mo júbà ó
Olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe

Ò fúrùrú lóòréré o
Àìláà Bàbá kényènyè ní Ejìgbò
Ilé Ìfọ̀n mo ti wá, Bàbá
Ejìgbò rere, mo júbà ó
Olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe

Ò fúrùrú lóòréré o
Àìláà Bàbá kényènyè ní Ejìgbò
Ilé Ìfọ̀n mo ti wá, Bàbá
Ejìgbò rere, mo júbà ó
Olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe

Ò fúrùrú lóòréré o
Àìláà Bàbá kényènyè ní Ejìgbò
Ilé Ìfọ̀n mo ti wá, Bàbá
Ejìgbò rere, mo júbà ó
Olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe

Àṣẹ, Bàbá
Ọlọrun orílẹ̀
Ọṣàlá bèsí fún ọ
Ẹ̀bẹ̀ Bàbá

Oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ
Onisá wure oberi omã
Oníṣà wúrè
Àwọn l’àṣẹ, Bàbá
Onisá wure oberi omã

Oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ
Onisá wure oberi omã
Oníṣà wúrè
Àwọn l’àṣẹ, Bàbá
Onisá wure oberi omã

Oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ
Onisá wure oberi omã
Oníṣà wúrè
Àwọn l’àṣẹ, Bàbá
Onisá wure oberi omã

O navio negreiro não foi
Um encontro marcado
A gente resiste
Por não ser cultura, no nosso país
Aquilo que deveria ter sido
Então, eu refaço esse caminho novamente

E, através desse novo navio
Encontra-se, na Bahia
E a gente, enfim, pode viver
A cultura africana no país chamado
Brasil

Otros videos de esta canción
    0 visualizaciones

    Afinación de los acordes

    Afinador en línea

    Ops (: Contenido disponible solo en portugués.
    OK