Cifra Club

Feel Good

Mohbad

Aún no tenemos los acordes de esta canción.

Ìmọlẹ
Plenty enemy (Mohbad)
Wey dey follow me
Májẹ k'ọ mú mí
Even if na dying minute

Èmi ọmọ ghetto
Mo tí d'aji lo motor (mo tí d'aji lo motor)
My grace na auto, automatic
Wọn fẹ bami ya photo (photo)

Èmi tí gbéra (on God)
Láti 4:30 (on God)
Wọn lé, wọn bà tí (on God)
Wọn mu, wọn filẹ (on God)
I drip on, jẹ k'onduro (on pause)
Ìmọlẹ (on God)
O wa'lẹ (on God)
(On God)

Ahn, when I dey Ikorodu, sapa mu mi
Mo má ronú
Mo má sunkún (mo má sunkún)
Ehn, I don work tire
I don pray tire
I don go Mountain of Fire, ah

I know there is a day
All my pains will go away
'Til then, I'll party away
I know there is a day
All my pains will go away
'Til then, I smoke it away
I feel good, pa, ran-ran, pa, ran-ran
ỌMọ ìyá mí, má lọ ronú o, ko pa, ran-ran, pa, ran-ran
I feel good (pa, ran-ran)

Èmi ọmọ ghetto (emi ọmọ ghetto)
Mo tí d'aji lo motor (mo ma tí d'aji lo motor)
My grace na auto, automatic
Wọn fẹ bami ya photo (photo)

Èmi tí gbéra (on God)
Láti 4: 30 (on God)
Wọn lé, wọn bà tí (on God)
Wọn mu, wọn filẹ (wọn mu, wọn filẹ) (on God)
I drip on, jẹ k'onduro (on pause)
Ìmọlẹ (on God)
O wa'lẹ (on God)
(On God)

Ìmọlẹ, o wa'lẹ
B'oṣe ń múlẹ, lọ ṣe ń jẹ
Lát'ayé tipẹ-tipẹ
Ìmọlẹ, o wa'lẹ
B'oṣe ń múlẹ', lọ ṣe ń jẹ
Lát'ayé tipẹ-tipẹ

Plenty enemy
Wey dey follow me
Májẹ kọ mumi
(Ìmọlẹ)
(Timi Jay on the track)

Otros videos de esta canción
    0 visualizaciones

    Afinación de los acordes

    Afinador en línea

    Ops (: Contenido disponible solo en portugués.
    OK