(Zed)
Ahn-ahn
Alákọri, alakọkọ, ṣ'ómá fẹ mí? Ṣ'ómá là tán?
Tí ń bà gbé wá (whoo), ṣ'ómá ká kọ?
Ṣé mo máa ní problem pẹlú boys?
Ta bà já, ká padà, má sá lọ Canada
If I travel today, kí ń má bà ẹ l'ababa (l'ababa)
Army man na my army man
Army man na my brother man
Ó lè ní problem
Ahh, baby, ṣ'ówa pá oh? (Ṣ'ówá pá?)
Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)
Mo láyé lo máa jẹ kù o
Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan)
Melanin poppin', baby, nìṣó ní tá
Baby, sunshine give you filter
Onidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu rarurábà
(Ṣ'owá?)
Ṣ'òní capital business? (Ṣ'owá?)
Ṣ'òní character deaconess? (Ṣ'owá?)
Can you wake up around 4: 30 (ṣ'owá?)
To make breakfast for me? (Ṣ'owá?)
Tó bà dálẹ, ṣ'olè gimme-gimme? (Ṣ'owá?)
Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ'owá?)
Gimme-gimme, k'oma gbọn mi jigi (ṣ'owá?)
Oh-ooh-oh
Long time ago, I say no kele fit make me conform, ooh-yah
Ò ká mí mọ corner (ṣ'ó)
Now, I won do am, now, I won run am (oya, uh)
Very gentle girl (whoo)
I'll pick you up, turn you biggie girl (biggie girl)
Mama say: I don fall in love
And my papa say: Ọmọ, jẹun lọ
Ahh, baby, ṣ'ówa pá oh? (Ṣ'ówá pá?)
Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)
Mo láyé lo máa jẹ kù o
Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan)
Melanin popping, baby, nìṣó ní tá
Baby, sunshine give you filter
Onidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu, rarurábà
(Ṣ'owá?)
Ṣ'òní capital business? (Ṣ'owá?)
Ṣ'òní character deaconess? (Ṣ'owá?)
Can you wake up around 4: 30 (ṣ'owá?)
To make breakfast for me? (Ṣ'owá?)
Tó bà dálẹ, ṣ'olè gimme-gimme? (Ṣ'owá?)
Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ'owá?)
Gimme-gimme, k'oma gbọn mi jigi (ṣ'owá?)
Oh-ooh-oh
(Ṣ'owá?)
(Ṣ'owá?)
(Ṣ'owá?)
(Ṣ'owá?) Oh-ooh-oh
(Ṣ'owá?)
(Ṣ'owá?)
(Ṣ'owá?)
(Ṣ'owá?) Oh-ooh-oh